HYMN 574

L.M (FE 601)
"Awa ko ni ilu ti o duro pe nihinyi
awa nwa okan ti mbo” - Heb.13:4



1.  A ko ni ‘bugbe kan nihin 

     Eyi ba elese n'nu je,

     Ko ye k’enia mimo kanu 

     Tori nwon nfe simi t’orun.


2.  A ko ni ‘bugbe kan nihin 

     O buru b'ihin je le wa 

     K’iro yi mu inu wa dun 

     Awa nwa ilu nla t’o mbo.


3.  A ko ni ‘bugbe kan nihin 

     A nwa ilu nla t’a ko ri 

     K’iro yi mu inu wa dun 

     Awa nwa ilu nla t'o mbo.


4.  Iwo ti nse ‘bugbe kan nihin 

     Ibiti ero gbe nsimi

     Emi ‘ba n’iye b’adaba 

     Mba fo sinu re, mba simi.


5.  Dake okan mi, ma binu 

     Akoko Oluwa l’oye

     T’emi ni lati se ‘fe Re

    Tire lati se mi l’ogo.  Amin



English »

Update Hymn