HYMN 493

C.M.S 510 t.H.C 336 11s (FE 516)
"Nibe ni eni-nuburu siwo iyonilenu, 
nibe eni-ara wa ninu isimi" - Jobu 3:17



1.  ISlMl wa l'orun, ko si l'aiye yi

     Emi o se kun, gbati yonu ba de 

     Simi, okan mi, eyikeyi t‘o de

     O din ajo mi ku, o mu k'ile ya.


2.  Ko to fun mi, ki nma simi nihinyi 

     Ki nsi ma kole mi ninu aiye yi

     Ongbe ilu t'a ko f'owo ko ngbe mi

     Mo nreti aiye ti ese ko baje.


3.  Egun esusu le ma hu yi mi ka 

     Sugbon emi ko Je gbara le aiye

     Emi ko wa isimi kan ni aiye

     Tit'eni o fi simi laiya Jesu mi.


4.  'Yono Je damu sugbon ko le pa mi 

     Oju 'fe Jesu le so 'yonu d'erin

     Erin Re le so ekun wa di ayo

     B'igba t'efufu fe ojo sisu lo.  Amin

English »

Update Hymn