Tune: C.M.S 491 H.C 215 C&F 3.Y.L.C 88 6s.5s (FE 455) “Maa wi nitori ti iranse re ngbo" - 1Sam.3:9 1. BA mi soro, Jesu Bi mo ti duro Fi okan mi le ‘le Ninu ireti. 2. Ba mi soro Baba Ni wakati yi Je ki nri oju Re Nin‘olanla Re. 3. Oro ti O ba so 'Oro iye ni Onje orun Ma bo mi titi. 4. Tire l’ohun gbogbo Nki si se t'emi Ayo ni mo fi wi Pe, Tire l'emi. 5. Fun mi ni imo na T'ise ogo Re Mu gbogbo ileri Re se s’ara mi. Amin