C.M.S 571 t.S. 86 C.M. (FE 445) "Eda ara mi ko pamo kuro lodo Re" - Ps. 139:15 1. TERUTERU t’iyanu ni Olorun mi da mi Gbogbo awon eya ara mi Ise iyanu ni. 2. Nigbat' a da mi n’ikoko O ti mo ara mi Eya ara mi l'O si mo Sa t’okan won ko si. 3. Olorun, iro inu Re Se ‘yebiye fun mi Iye won poju iyanrin Ti ko seni le ka. 4. B’o ti mo eda mi bayi Wadi okan temi Mu mi mo ona Re lailai Si ma to ese mi. Amin