C.M 1. BABA anu, n’nu am Re L‘ogo ailopin ntan K’a ma yin oruko Re lai Fun iwe mimo yi. 2. N’nu re l’awon alaini le Ri oro ailopin Oro, t’aiye ko le fun-ni T'o daju bi iye. 3. N‘nu re n’igi imo rere Nfun-ni l’onje ofe T'adun re po ju t’aiye lo To nfa gbogbo eda. 4. N'nu re l’a gbo t’Oludande Nkede alafia Iro didun na je iye At'ayo ailopin. 5. Oluwa, Oluko mimo Ma sunmo mi titi Ko mi lati fe oro Re Ki nri Jesu nibe. Amin