HYMN 334

8s 75s (FE 357)
Tune: ‘E gbohun ife at‘anu



1.  ALLELUYAH! O ti jinde 

     Jesu goke lo s'orun

     O si fo itegun esu

     Angeli ho, enia dahun.

Egbe:  O ti jinde, O ti jinde 

           O Wa laye, ko ku mo.


2.  Alleluyah! O ti jinde 

     Eniti o ga julo

     Jeri si Emi na wipe

     On ni alagbawi wa,

Egbe:  O ti jinde, O ti jinde fun

            Awa t'a da lare.


3.  Alleluyah! O ti jinde 

     lku ko tun n‘ipa mo 

     Kristi papa ni Ajinde 

     Yio si m‘awon Tire wa. 

Egbe:  O ti jinde, O ti jinde fun

            Oluwa Oba Iye.  Amin

English »

Update Hymn