HYMN 219
"Iyin si Olorun" - Ps.146:2
A wa yinO/Olorun; awa njewo Re pe
I-wo li Oluwa,
Gbogbo aiye fi ori ba/le fun O:
Baba/aiye titi lai.
Iwo li eniti gbogbo awon Angeli/nkigbe pe: Orun
ati gbogbo agbara/ti mbe ninu won.
Iwo Ii eniti awon kerubu ati awon/Serafu:
kigbe pe/nigbagbogbo pe.
Mimo, Mimo, Mimo: Oluwa Oloruna/won
omo-ogun;
Orun/on aiye kun fun o/la nla ti ogo Re
Egbe awon Aposteli ti‘o l'ogo: yin-O,
Ogba awon woli ti o dara: yin - O,
Ogun awon Ajeriku ti‘o l’ola: yin - O,
ljo mimo enia Olorun ni gbogbo aiye, njewo -Re:
Ba/ba: eni ola nla/ti ko nipekun
Ali omo Re ni/Kansoso: o/lola oloto:
Emi/Mimo pelu; O/lutunu.
Kristi, iwo li’Oba ogo:Iwo Ii Omo lailai ti Baba,
Nigbati iwo tewogba a fun are Re Iati gbe enia la:
Iwo ko korira/inu wundia,
Nigbati Iwo segun oro/iku tan: Iwo si ljoba Orun
sile fun gbogbo a/won onigbagbo
Iwo joko lowo otun/Olorun: ninu/ogo ti Baba.
Awa gbagbo pe I/wo mbo wa lati se/Onidajo wa.
Nitorina Ii awa se ngbadura sodo Re, ran awon omo
Odo/Re lowo:ti Iwo ti fi eje Re iye/biye ra pada.
Se won lati ka won kun awon enia/mimo Re: ninu
ogo/ti ko nipekun.
Oluwa, gba awon e/enia Re la:ki Iwo ki o si fi ibukun
fun awon/enia ini Re,
Jo/ba won: ki Iwo ki o ma gbe/won soke lailai.
Awa ngbe/Iwo ga; lo/jojumo;
Awa si nfi' ori bale li o/ruko Re; titi aiye/ti ko nipekun
Fiyesini/Oluwa; lati pa wa mo lo/ni li ailese,
Oluwa/ sanu fun wa; sa-/nu fun wa
Oluwa je ki anu Re ki o ma/ba le wa:
gebebi awa ti ngbeke wa le O.
Oluwa, Iwo ni mo/gbekele; Iai ma jeki ng damu. Amin
English »Update Hymn