1. OLUWA awa de Kerubu, Serafu Lati je ise to ra wa Fun gbogbo agbaiye. 2. lse t’o ran l’eyi Olorun Oluwa P’a won ti nb’ojo isimi je Ni yio jebi poju. 3. K’araiye teriba Niwaju ase Re K’ibinu Olodumare Le ka kuro l’aiye. 4. Kerubu Serafu Enyin n’iyo aiye Iluu t’a te sori oke Yio ti se farasin. 5. E fun ‘pe na kikan Nipa t’ojo isimi Ki gbogbo orile-ede Le p’ojo Mimo mo. 6. E f'Ogo fun Baba E f'Ogo fun Omo E f'Ogo fun Emi Mimo Metalokan lailai. Amin