HYMN 861

OMO EGBE SERAFU DIDE



1.  OMO Egbe Serafu dide 

     F'ife at'aniyan dide

     Jeki imole re tan roro 

     Dide lati gbe Jesu ga.

Egbe: Ma yan nin'ola Olorun wa 

          Ma yan nin'oIa Olarun wa 

          Ma yan, ma yan

          Ma rin, ma yan n'nu ‘fe Jesu.


2.  Omo Egbe Serafu dide 

     F'ayo ru agbelebu re

     Ma binuje, ma b’ohun bo

     Jesu y’o s’ekun re d’ayo.

Egbe: Ma yan nin'ola...


3.  Omo Egbe Serafu dide 

     Ireti re ko ni saki

     Baba ko ni ko ohun re 

     Mase je ko re ‘gbagbo re.

Egbe: Ma yan nin'ola...


4.  Omo Egbe Serafu dide 

     Oke nla yio di petele 

     Bi Olorun ba nse tiwa 

     Tani le doju ‘jako wa.

Egbe: Ma yan nin'ola...


5.  Omo Egbe Serafu dide 

     Jesu Oluwa fere de 

     Ade ‘rawo yio je tiwa 

     Larin Egbe Mimo t‘orun.

Egbe: Ma yan nin'ola Olorun wa 

          Ma yan nin'oIa Olarun wa 

          Ma yan, ma yan

          Ma rin, ma yan n'nu ‘fe Jesu.  Amin

English »

Update Hymn