CM 1. OLORUN, ‘ranwo eni Re Reti wa n‘igba bi A gba ‘Wo Eni Airi gbo Awa nwa O sibe. 2. Ese ti awon elese Nfojudi ipa Re Ti won si nhale b'enipe ‘Wo ko ri ese won. 3. Oluwa, dide k'o gba wa A m'oran wa t'O wa F‘ododo at'ipa joba Wo nikan Ii Oba. 4. Iwo mo gbogbo ife wa ‘Ranwo Re wa n‘tosi Pese okan wa f'adura Si gba adura wa. Amin