HYMN 858

7.7.7.7.D



1.  MO mbo nib agbelebu
 
     Emi abosi julo

     Mo ka gbogbo nkan s‘ofo

     Lati ri gbala kikun.

Egbe: Mo gbekele O, Jesu

          Odagutan Kalfari

          Mo fi 'rele teriba

          Gba mi, Jesu loni yi.


2.  Mo gbekele 'leri Re 

     At'agbara eje ni

     Mo pon ara mi l'oju 

     Mo ru agbelebu Re.

Egbe: Mo gbekele O...


3.   Jesu fi ayo kun mi 

     O si so mi di pipe

     Mo ni ilera pipe

     Ogo ni f‘od'agutan.

Egbe: Mo gbekele O, Jesu

          Odagutan Kalfari

          Mo fi 'rele teriba

          Gba mi, Jesu loni yi.  Amin

English »

Update Hymn