C.M.S 465 H.C 503 7s (FE 974) “O gbe owo Re le won O si sure fun won" - Marku 10:16 1. JESU fe mi, mo mo be Bibeli l‘o so fun mi Tire l‘awon omode Nwon ko lagbara, On ni. 2. Jesu fe mi En’to ku Lati si orun sile Yio we ese mi nu Jeki omo Re wole. 3. Jesu fe mi sibe si Bi emi tile s‘aisan Lor'akete aisan ni Y’o t‘ite Re wa so mi. 4. Jesu fe mi, y’o duro Ti mi ni gbogb’ona mi Gba mba f’aiye yi sile Y’o mu mi re ‘le orun. Amin