C.M (FE 870) Awo ati, ija ohun ti ko dara ni 1. A JA ni gbo-Ekun aja Be l‘a sa s‘ede won Ogidan, l'ola iju L‘akomo l'ain obe. 2. Sugbon enia l’a da nyin E hu wa bi omo K‘e mase ba ara nyin ja Ere ni k’e ma se. 3. Bi Omo-rere Maria Ni k’iwa nyin tutu K’e po n’ife bi Oluwa Jesu Om'Olorun. 4. Eni jeje bi agutan Ti iwa Re wun ni Enia ati Olorun N’idagba Re si won. 5. Oluwa gunwa bi Ona L'ori ‘te Re lorun O nwo aw' omo t‘o n'ife O si nsami si won. Amin