HYMN 83

(FE 100)
"Oluwa on Ii Olorun wa" - Ps 105:7



1.  A DUPE lowo Olorun

     T'o da wa si d'oni

     T‘o je k‘emi tun emi ri,

     Ogo f’oruko Re.

Egbe:  A dupe lowo Olorun

           T'o da emi wa si d'oni

           T’o je k'emi tun emi ri

           Ogo f'oruko Re.


2.  Ise po n'ilu Osogbo

     T'ilesa ko ni so;

     Egbe Ondo ti mura tan

     Lati gbe Jesu ga.

Egbe:  A dupe lowo Olorun...


3.  Egbe Eko damure nyin,

     Lati besu jagun;

     Oko pon pupo n'ilu Oke,

     Tani yio lo ka?

Egbe:  A dupe lowo Olorun...


4.   A ki Baba Aladura

     O ku afojuba

     Olori ti jagun fun Jesu,

     O si segun Esu.

Egbe:  A dupe lowo Olorun...


5.  Orin Halle, Halleluya

     L’awa y'o ko l‘orun

     Nigbat' a ba r'Olugbala,

     Ni ori ite Re.

Egbe:  A dupe lowo Olorun...  Amin

English »

Update Hymn