(FE 863) "Silekun fun wa" - Matt. 25:11 1. SILEKUN fun wa o - 2ce Iwe lo ni wa Mase ta wa nu Silekun fun wa o. 2. Wa pese fun wa o - 2ce lwo lo ni wa Jehofa-Jireh Wa pese fun wa o. 3. Wa f‘oyin s‘aiye wa - 2ce Iwo l'o l‘aiye Jehova-Nissi Wa f'oyin s'aiye wa. 4. Ma jek’ a sonwo lo - 2ce Bukun fun wa se Jehova‐Barak Ma je k’a sonwo lo Amin o! Ase, beni k’o ri o. Amin