(FE 858) “Nitoripe odo Re li emi o ma gbadura si" - Ps. 5:2 1. EGBE lye l’Egbe Seraf, Egbe Adura ni Egbe ti ko gbeke l’egbo Egbe ti ko gbekel’ ewe Kristi nikan ni ‘Mole On l’Oluwosan won. 2. Enyin Olori Egbe Seraf E s’otito d’opin Ati gbogb’Egbe Aladura Ati Baba nla mejila E ma wo ‘ya, e ma w’egan Ke le gbade Ogo. 3. Jesu Oba Egbe Seraf’ Ma je ka padanu L’ojo ta o se ‘dajo aiye T’oju aiye, orun yio pe, Messiah Nla Oba Ogo, Je ka le d’odo Re. Amin