HYMN 815

(FE 851)
"Gba mi kuro li enu kiniun ni”
 - Ps.22:21
Tune: K & S 187



1.  OLORUN Alagbara nla

     T’O p’ara Egypt run

     L’eti okun nijokini 

     P'agbara Ota mi run.

Egbe: Jowo gbe mi leke 

          Ma jek'ota bori mi

          Segun, gbogbo ota fun mi,

          Gbe mi leke ‘danwo.


2.  Jesu, loni mo kepe O, 

     Baba mi gbo temi

     Segun gbogbo' ogun ti mo ri

Egbe: Mase jeki nseku

          Mu ki Ifoiya mi lo

          F'okan mi bale lat'oni 

          K’ota ma le mi mo.


3.  Jesu Olori Egbe wa, 

     Wo ni mo gbekele 

     Lai, ma jeki oju ti mi 

     Pese fun aini mi.

Egbe: Baba, mo sa di O 

          S’aiye mi ni rere

          Ki ikolu tabi ikolo 

          Mase subu Iu mi.  Amin

English »

Update Hymn