S.M. (FE 845) “Gbogbo aiye ni yio ma sin O" - Ps.66:4 1. WA, rohin Re yika K’a si korin ogo Alagbara li Oluwa Oba gbogbo aiye. 2. On l'O da won ibu O pala fun okun Tire ni gbogb’ awon odo At'iyangbe ile. 3. Wa, wole n’ite Re Wa, juba Oluwa lse owo Re l‘awa se, Oro Re l'o da wa. 4. Gbo ohun Re loni Ma si se mu binu Wa, bi eni ayanfe Re Jewo Olorun re. Amin