HYMN 808
(FE 843)
“E pese okan nyin sile” - 1Sam. 7:3
1. ENYIN araiye gbo
igb’aiye ku si dede
E jek’ a sin Jesu k’aiye to lo
E ba je k'a kole, ile ayo si oke
K’a mase k‘abamo ni igbehin o.
Egbe: Olu se wa ye, jowo wa
se wa ye f'orun, - 2ce
K‘a Ie gbo ohun ni pe,
O seun
K’a Ie sin O loke o, Oba wa.
2. Enit' o ba l’eti k’o lo yi ‘wa
re pada
K'o lo mura si ‘se rere ise
Ekan t'aiye ba bo, ko tun si
atunse mo o,
E jek’a ronu o, k‘aiye to lo.
Egbe: Olu se wa ye...
3. E jek'a sa f'aiye, ko tun
s’adun ninu re
E je k’a dojuko ile orun
Ofo Ii o gbamu, enti’o
waiye m'aiya
E jek'a f’aiye ‘le ka sin Jesu.
Egbe: Olu se wa ye...
4. Eda t’o wa s'aiye, wa se wa
ye fun orun
Jeki a sin O o b'o ti to
Nigbat' aiye ba bo, ko tun
si atunse mo o
Jek' a ba O gbe po n’ile orun.
Egbe: Olu se wa ye, jowo wa
se wa ye f'orun, - 2ce
K‘a Ie gbo ohun ni pe,
O seun
K’a Ie sin O loke o, Oba wa. Amin
English »Update Hymn