(FE 842) “Orin isedale Egbe Kerubu ati Serafu Mimo, ti a da sile lati owo Alagba wa, Moses Orimolade” 1. LOKE odo Jordani L’a pe mi - 2ce Awon olufe mi to ti lo, to ti lo Mo fe lo ba won wole ogo A ki yo ya mo titi lailai lailai Wo sile, wo sile ife Iwe Jesu so fun mi pe Angeli gbe mi lo mo ayo, Jesu si mu mi wole. Amin