Tune: 7s 1. E fi ogo fun Baba Nipa Eni ti a wa O ngbo adura ewe O nf’eti si orin won. 2. E fi ogo fun Omo Kristi, ‘Wo ni Oba wa E wa, e korin s’oke S’Od’agutan elese. 3. Ogo fun Emi Mimo Bi ojo Pentikosti Ru aya awon ewe F’orin mimo s’eti won. 4. Ogo ni l’oke orun Fun Eni Metalokan Nitori ihin rere Ati ife, Olorun. Amin