HYMN 801
1. MO n fe O n‘gha gbogbo
Oluwa Oloore
Ko s'ohun ti n fun ni
N’sinmi bii Re.
Egbe: Mo n fe, o aah! mo n fe O
Ni wakati gbogbo
Bukun mi Olugbala
Mo wa do Re.
2. Mo n fe O n'gba gbogbo
Duro ti mi
Idanwo ko nipa
B’o wa n’tosi.
Egbe: Mo n fe...
3. Mo n fe O n'gba gbogbo
N'ipokipo
Yara wa ba mi gbe
Ki n ma p'ofo
Egbe: Mo n fe...
4. Mo n fe O n‘gba gbogbo
F’ife Re han
K‘O je k'ileri Re
Le se si mi
Egbe: Mo n fe...
5. Mo nfe O n’gba gbogbo
Eni Mimo julo
Se mi n’ ti Re tooto
Omo Olorun.
Egbe: Mo n fe, o aah! mo n fe O
Ni wakati gbogbo
Bukun mi Olugbala
Mo wa do Re. Amin
English »Update Hymn