HYMN 800

C.M.S. 593 S. 81 P.M (FE 835)
“K’Ore-ofe Jesu kristi Oluwa wa
K’o pelu gbogbo nyin” - 1Kor. 16:23




1.  ORE-OPE! ohun

     Adun ni l’eti wa, 

    Gbohun-gbohun re y’o 

    gba orun kan, 

    Aiye o gbo pelu.

Egbe: Ore-Ofe sa,

          N’igbekele mi,

         Jesu ku fun araiye,

         O ku fun mi pelu.


2.  Ore-Ofe l’o ko

     Oruko mi l'orun

     L'o fi mi fun Od’agutan, 

     T’o gba iya mi je.

Egbe: Ore-Ofe sa...


3.  Ore-ofe to mi,

     S’ona alafia;

     O ntoju mi, lojojumo, 

     Ni irin ajo mi.

Egbe: Ore-Ofe sa...


4.  Ore-Ofe ko mi, 

     Bi a ti gbadura,

     O pr :ni mo titi d‘oni 

     Ko si jeki nsako.

Egbe: Ore-Ofe sa...


5.  Jek' ore-ofe yi, 

     F’agbara f’okan mi;

     Ki nle fi gbogbo ipa mi, 

     At’ojo mi fun O.

Egbe: Ore-Ofe sa,

          N’igbekele mi,

         Jesu ku fun araiye,

         O ku fun mi pelu.  Amin

English »

Update Hymn