O.t.H. C. 289 C.M. (FE 829) "E mase fe aiye" - 1John. 2:15 1. AWA fe ohun aiye yi Nwon dara l‘oju wa A fe k‘a duro pe titi Laifi won sile lo. 2. Nitori kini a nse be? Aiye kan wa loke Nibe l'ese on buburu Ati ewu ko si. 3. Aiye t’o wa loke orun Awa iba je mo Ayo, ife inu rere Gbogbo re wa n’be. 4. Iku, o wa ni aiye yi Ko si loke orun Eniyan Olorun wa mbe Ni aye ni aiku. 5. K’a ba ona ti Jesu lo Eyi t'O la fun wa Sibi rere, sibi simi S’ile Olorun wa. Amin