C.M (FE 822) 1. OGO OBA wa ti po to Ti mbe l’oke orun, Omo-kekere wo l’o le, Korin ola ‘nla Re. 2. Ta l’o le rohin ipa Re At’ore-ofe Re Ko s’enikan l’aiye l’orun To mo titobi won. 3. Angeli t’o yi Oluwa ka Ko je so ‘tumo re Sugbon nwon npa ase re mo Nwon si nkorin ‘yin Re. 4. Nje mo fe ma ba won korin Ki nm’ore temi wa Oga-Ogo ki y’o kegan Ohun orin ewe. 5. Mura, okan at'o ahno mi, Lati korin iyin S’Olodumare Eleda Ayo aw’Angeli. Amin