HYMN 784

8.7.8.7 D
Tune: ’Tori mi ati ’hinrere



1.  Mo I‘Ore kan, ife Re po 

     O fe k‘emi t‘o m‘O

     Okun ife I'O fi fa mi

     O si de mi mo ‘ra Re 

     Koko ‘fe re, t‘a ko le tu 

     Lo mo okan mi sibe 

     Mo je Tire, On je temi 

     Lae ati titi laelae.


2.  Mo l‘Ore kan, ife Re po 

     O ku lati gba mi la

     lye nikan ko l‘o fun mi 

     O fi ara Re ji mi

     Nko ni p‘ohun kan ni temi 

     Un o pamo f'Olufunni 

     Okan, agbara, emi mi 

     Tire, ni titi laelae.


3.  Mo l‘Ore kan, ife Re po 

     Gbogb’agbara l'a fi fun 

     K'O le so mi li ajo mi 

     K‘O si mu mi de orun 

     Ogo ailopin ntan ‘mole

     Lati fun mi li okun

     Un o sora, un o sise, un o ja 

     Lehin na, un o simi lae.


4.  Mo I‘Ore kan, ife Re po 

     Oniyonu, Oloto 

     Olugbimo at‘Amona 

     Alabo t'o lagbara

     Kini ‘ba le ya mi lodo

     Eni fe mi po to yi

    lye‘ Iku? aye, egbe

    Beko, Mo je Tire lae.  Amin

English »

Update Hymn