C.M.S 545 t.H.C 60 7s (FE 816) "Emi ki gbe pe O, Oluwa” - Ps.30:8 Tune: A gboju s’oke si O 1. WA, Jesu fi ara han, Wa, jek'okan wa mo O Wa, mu gbogb’okan gbona Wa, bukun wa k‘a to lo. 2. Wa, f’aiya wa n’isimi Wa, k’a d’alabukunfun Wa, soro alafia Wa, busi igbagbo wa. 3. Wa, le ‘siyemeji lo Wa, ko wa b’a ti bebe Wa, fun okan wa n'ife Wa, fa okan wa soke. 4. Wa, so f‘okan wa k‘o yo Wa, wipe “Wo ni mo yan Wa, p'awon agbo Re mo Wa, sure f’agutan Re. Amin