C.M.S 592 S.M. (FE 804) "E ma ko won lati ma kiyesi ohun gbogbo" - Matt. 28:20 1. ENYIN ‘ranse Kristi Gbo ohun ipe Re E tele bi t’o fonahan A npe nyin s‘ona Re. 2. Baba ti enyin nsin O n’ipa to fun nyn N‘igbekele ileri Re E ja bi okunrin. 3. Lo f’Olugbala han Ati anu nla Re F’awon otosi elese Ninu omo Adam. 4. L’oruko Jesu wa A ki nyin, Ona re! A mbe Enit’ o ran nyin lo K’O busi ise nyin. Amin