HYMN 764

C.M.S 521 C.M (FE 798)
“Isise kan ni mbe larin emi ati iku”
- 1Sam. 20:3



1.  ODUN nyipo, o ji emi 

     T’O ti fi fun wa ri 

     Ibikibi to wu ka wa 

     Isa-oku la nre.


2.  Yi ile ka l’ewu duro 

     Ko le ti wa s‘isa 

     Arun buburu si duro 

     Lati le wa lo ‘le.


3.  Ayo tab’egbe ailopin 

     Duro de emi wa

     Wo! ba ti nrin laibikita 

     Leti bebe iku.


4.  Oluwa, ji wa l’orun wa 

     K’a r’ona ewu yi 

     Nigbat’ a ba pe okan wa 

     K’a ba O gbe titi.  Amin

English »

Update Hymn