C.H. 372 t.H.C 140 C.M (FE 789) “Alabukun fun li awon oku ti o ku nipa ti Oluwa” - Ifi.14:13 1. GB'ohun t’o t‘orun wa ti wi F’awon oku mimo Didun n‘irant’oruko won Busun won n’itura. 2. Nwon ki n’nu Jesu abukun Orun won ti dun to! Ninu irora on ese Nwon yo ninu danwo. 3. Lona jijin s’ayie ise Nwon mbe lod’Oluwa Ise won l‘aiye iku yi Pari li ere nla. Amin