HYMN 746

t.S 65 P.M (FE 774)
“E fi ope fun Oluwa, nitoriti O seun, 
nitoriti anu Re duro laiIai" - Ps.107:1
Tune: “Ojo Nla Lojo Ti Mo Yan.”



1.  OJO nla l‘ojo t’Oluwa 

     Da egbe Serafu sile

     O ye ki awa ko ma yo

     Fun ‘fe t‘Olorun ni si wa. 

Egbe: Ojo nla l’ojo na,

          T’Olorun d‘egbe yi sile

          O nko wa ka ma gbadura, 

          K’a n’ife si enikeni

          Ojo nla I’ojo na

          T'Olorun d’egbe yi sile.


2.  Gbogbo aiye, e ba wa yo 

     Fun ‘fe t’Olorun ni f’aiye

     Enyin ta pe si egbe yi

     E fi ayo korin soke 

Egbe: Ojo nla l’ojo na...


3.  Ki kerubu fe Serafu, 

     Ki Serafu fe Kerubu

     O ye k’awa ko ma yo

     Fun ‘fe t’Olorun ni si wa.

Egbe: Ojo nla l’ojo na,

          T’Olorun d‘egbe yi sile

          O nko wa ka ma gbadura, 

          K’a n’ife si enikeni

          Ojo nla I’ojo na

          T'Olorun d’egbe yi sile.  Amin

English »

Update Hymn