HYMN 742

8s 4s (FE 768)
"Jeki Israeli ki o yo si eniti o da”
 - Ps. 149:2



1.  KERUBU ati/Serafu 

     Nwon nyin Baba/wa loke 

     Baba Mimo, Baba/ogo 

     ko so wa.


2.  Jesu Olori/Egbe wa 

     O ti ji di/de loni 

     Kerubu ati Se/rafu 

     Kun fun ayo.


3.  Jehovah Ji/reh Oba 

     Jehovah Nis/si Baba 

     Jehovah-Rufi/yio so wa 

     Titi lailai.


4.  Enyin omo egbe/Kerubu 

     To wa lori/’le aiye
 
     Jesu Olori Egbe wa, 

     Jinde loni.


5.  Egbe to ndamu/nisiyi 

     To si ngbadu/ra kikan 

     Yio bu s’orin a/yo lojo 

     Ajinde.


6.  Egbe Mimo to/wa l’oke 

     Nwon nyin Baba/wa logo 

     E je k’awa ta/wa laiye 

     Ka si mura.


7.  Aje, Oso ko ni/ipa kan 

     Lori Egbe/Kerubu, Seraf 

     Jesu Olori/Egbe wa,

     O ti segun.  Amin

English »

Update Hymn