t.H.C.120 D.8s 7s (FE 760) "Iwo ma beru, nitori mo wa pelu re“ - Isa. 41:10 1. EGBE Serafu, e dide E d’amure nyin giri Olorun lo d’egbe yi sile E ma jek‘eru ba yin Lo wasu ihinrere Re, Yio pelu wa titi d’opin, Ke sa ma wo Jesu li okan Titi ao fi segun. 2. Egbe Serafu, e dide Lati tan oro Olorun Papa larin ilu Eko F’awon to ti sako Io Ka le d’eni irapada Larin awon ti o nsegbe lo Lati ran won s’agbo Jesu Si iye ainipekun. Amin