HYMN 730
H.C 117 6s (FE 756)
"E mase beru won" - Deut. 1:29
“Orin yi wa fun akoko wahala lehin
kiko we a o ka Psalm 14,144,191.
Ohun Orin “Kristi k’ijoba Re de”
1. MAIKIEL Olusegun
Yara sokale wa
Loni n'isegun re
Mase duro pe mo.
2. lsegun re, baba
O po ju t‘enia
Jehora Oba wa
Segun iku fun wa.
3. Ogun aje gbona
Ogun oso gbona
Asahola-Hurah
Wa segun ota wa.
4. Apejuba-Hujjah
Yawotah-Saharah
Enyin onida ina
Segun aje fun wa.
5. Iyamma-Iyanna
Oba ‘Lewilese
Ajagorah-Hullah
P’agbara aje run.
6. Enyin Kerubu orun
At‘enyin Serafu
E nde fun iranwo
Awa t’aginju aiye.
7. Emmanuel Baba
Olusegun iku
Oba aiku ni O
Yara wagba wa la.
8. Ojira-Saro-Fa
Eli-Eli-Yaworah,
Oba ‘wimayehun
Wa se t’emi n’ire.
9. Ogo ni fun Baba
Ogo ni fun Omo,
Ogo f‘Emi Mimo
Metalokan lailai. Amin
English »Update Hymn