7775 1. OLORUN Metalokan Oba ile at’okun Gbo ti wa bi a nko Orin iyin Re. 2. Wo imole l‘owuro Tan ‘mole Re yi wa ka Jeki ebun rere Re M'aya wa bale. 3. Wo ‘mole nigb‘orun wo K'a ri idariji gba Ki alafia orun F'itura fun wa. 4. Olorun Metalokan lsin wa l’aye ko to A nreti lati dapo Mo awon t'orun. Amin