8.7.8.7.4.7 Tune: Ma toju mi Jihofah Nla 1. OGO fun Olorun Baba Ogo f’Olorun Omo Ogo fun Olorun Emi Jehofa, Metalokan Ogo, Ogo B’ayeraye ti nkoja. 2. Ogo fun Eni t’o fe wa T‘o we abawon wa nu Ogo fun Eni t’o ra wa T’o mu wa ba On j’Oba Ogo, ogo Fun Od’agutan t’a pa. 3. ’Ogo, bukun, iyin laelae L’awon ogun orun nko 'Ola, oro, ipa, ‘joba! L’awon eda fi nyin I, Ogo, ogo, Fun Oba awon Oba. Amin