HYMN 71
CM
"Oluwa sanu fun mi” - Ps. 123:3
1. GBANGBA l‘oju Re Olorun
S’Ohun gbogbo ta use,
T'osan t'oru bakanna ni,
L'oju Oluwa wa.
2. Ko s’ese kan ti a le da
Ko s’oro t'a le so
Ti ko si ninu iwe Re
Fun iranti gbogbo.
3. Ese ole, ese iro
Ese aiforiji
Ese ka soro eni lehin
Baba dariji wa.
4. Ese igberaga okan
Ese isokuso
Ese aini ‘gbagbo daju
Baba dariji wa.
5. A! l'ojo nla ojo ‘dajo
Ma je k‘oju tiwa
T'oju gbogbo aiye yio pe
Baha dariji wa.
6. Dariji mi Olorun mi,
Ki nto lo laiye yi,
Si pa gbogbo ese mi re
Baba danriji mi. Amin
English »Update Hymn