H.C 231:tabi t.H.C 205. D.C.M "Oluwa awon omo-ogun, On na Ii Oba ogo" - Ps. 24:10 1. GBE ori iyin s’oke, eyin ‘Lekun aiyeraiye: Gba oba ogo: wo, o mbo Pel’ogun orun Re. Ta l'Oba Ogo yi? Tani? Oluwa t'o ni ipa T’o lagbara l’o or’ota Re Asegun, Alade. 2. Gbe ori yin s‘oke, enyin Ilekun; lati gbaa Oba ogo, pe we, o mbo Pel’ ogun didan Re Tal’oba Ogo yi? Oluwa t‘o n’ipa L’ogo on nikan Ii oba Ta f'ogo de l’ade. Amin