C.M. (FE 712) “Iwa ole, ohun buburu bi" 1. WO alapon kokoro ni N’nu gbogbo itanna Bi o ti nfa oyin jade Lara ewe gbogbo! 2. W’onje didun ti o nkojo Si inu ile re! Wo, b‘o ti se f’ara re da Wo ida didan re! 3. Be l’o ye ki nma se apon N'nu gbogbo ise mi Esu ki s’alairi ‘se kan T'o buru f'ole se. 4. Ngo ma ko iwe l’akoko Lat'igba ewe mi Ngo si mura si ise mi K’oju ma ba ti mi! Amin