461 H.C 493. 6s 5s "Tani ha nkegan ohun ojo kekere" - Sek. 4:10 1. OPO ikan omi Yanrin kekeke Wonyi l‘o d’okun nla At'ile aiye. 2. Iseju wa kokan Ti a ko ka si Lo d'odun aimoye Ti ainipekun. 3. lwa ore die Ore'fe die L‘o ns‘aiye di Eden Bi oke orun. 4. lsise kekeke Lo nmokan sina Kuro l’ona rere Si ipa ese. 5. lse anu die T’a se l’omode Di ‘bukun f'orile To jina rere. 6. Awon ewe logo Ngberin Anglei Se wa ye, Oluwa, F'egbe mimo won. Amin