C.M.S 482 t. H.C. 36.8s (FE 710) "E fi iberu sin Oluwa” - Ps. 2:11 1. OMODE, e sunm’ Olorun Pelu irele at’eru Ki ekun gbogbo wole fun Olugbala at'Ore wa. 2. Oluwa, je k’anu Re nla Mu wa kun fun ope si O Ati b‘a ti nrin lo laiye K‘a ma ri opo anu gba. 3. Oluwa! m‘ero buburu Jina rere si okan wa L;'oiujumo fun wa I‘Ogbon Lati yan ona toro ni. 4. lgba aisan at‘ilera lgba aini tabi oro Ati lakoko iku wa Fi agbara Tire gba wa. Amin