C.M.S 483 C.M. (FE 709) "E yin Olorun wa, enyin iranse Re ati ewe ati agba" - Ifi. 19:5 1. OLORUN orin, eniti Awon Angeli nko Wo ‘le lati bujoko Re! Ko wa k'a beru Re! 2. Oro mimo Re la fe ko Lat‘ igba ewe wa K'a ko t’Olugbala t’ise Ona, lye, Oto. 3. Jesu, ogo at‘ore Re L‘a nso nisiyi Se ‘bujoko Re s'okan wa Si je k’a beru Re. Amin