HYMN 682

C.M.S 486 P.M (FE 707)
“Ojo nlo, ojiji ale na jade" - Jer. 6:4



1.  OJ’ON lo, 

     Jesu, Baba

     Boju Re w‘emi omo Re.


2.  Wo Imole

     Se ‘toju mi

     Tan imole Re yi mi ka.


3.  Olugbala

     Nko ni beru

     Nitori O wa lodo mi.


4.  Nigbagbogbo

     Ni oju Re

     Nso mi, gbat’ enikan ko si.


5.  Nigbagbogbo

     Ni eti Re,

     Nsi si adura omode.


6.  Nitorina

     Laisi foiya

     Mo sun, mo si simi le O.


7.  Baba, Omo

     Emi Mimo

     Ni iyin ye I‘orun, laiye.  Amin

English »

Update Hymn