HYMN 68

S.S 896 (FE 86)
“Oluwa apata mi ati Oluadande mi”
- Ps. 19:14



1.  NGO korin ti Oludande mi

     Ati ife iyanu Re,

     O jiya lori ‘gi oro

     Lati so mi dom’nira.

Egbe:  Korin ti Oludande mi,

           Eje Re l’o fi ra mi

           O f’ote re-dariji mi

           O sanwo-mo dom’nira.


2.  Emi o so’tan Iyanu Re,

     B’o ti gbogun mi to ni

     Nu ‘fe at'anu ailopin

     Fi ‘dande fun mi lofe.

Egbe:  Korin ti Oludande mi...


3.  Ngo y’Oludande mi owon

     Ngo r’agbara segun Re

     B’o ti fun mi ni isegun

     Lor’ese at’iparun.

Egbe:  Korin ti Oludande mi...


4.  Ngo korin t’Oludande mi,

     T'ife at'orun wa Re,

     O mu mi la’ku si ye

     Lati ba om’Olorun gbe.

Egbe:  Korin ti Oludande mi... Amin

English »

Update Hymn