HYMN 676

t.H.C 577 6s 8s (FE 702) 
Tune: Oluwa yio pese



1.  IYA l'olore mi

     Ti ntoju mi Iaiye

     Ti ngbe mi pon losan

     Ti nsun ti mi loru. 

Egbe: Iya ku ise

          Nigbawo ni

          Ngo f'ope fun o 

          Fun' toju mi?


2.  Eni bi ‘ya ko si 

     Ninu gbogb‘ebi mi 

     K‘Olorun da mi si 

     Ki nto iya temi. 

Egbe: Iya ku ise...


3.  Baba ni jigi mi 

     Iya mi ni wura

     Ti nsun ti mi loru 

     Ti ngbe mi pon kiri. 

Egbe: Iya ku ise...


4.  Bi mo l’ogbon laiye 

     O wa lowo ‘ya mi

     Bi mo si alagbon

     Ebi iya mi ni.

Egbe: Iya ku ise

          Nigbawo ni

          Ngo f'ope fun o 

          Fun' toju mi?  Amin

English »

Update Hymn