HYMN 674
C.M.S 487 C.M (FE 700)
ILE EKO 0J0ISIMI
"Iml mi dim nigbati nwon wifwt mi pe, Ejeka10si[la Oluwa"-PS.112:1
1. ILE-EKO ojo ‘simi
A, mo ti fe o to
lnu mi dun mo daraya
Lati yo ayo re.
2. Ile-eko ojo’simi
Ore re papoju
T‘agba t‘ewe wa nkorin re
A nse aferi re.
3. lle-eko ojo' simi
Jesu l’o ti ko o
Emi Mimo Olukoni
L’o si nse ‘toju re.
4. lle-eko ojo’ simi
Awa ri eri gba
P‘Olorun Olodumare
F’ibukun sori re.
5. Ile-eko ojo simi
B‘orun nran l’aranju
Bi ojo su dudu lorun
Ninu re l’emi o wa.
6. lle‐eko ojo’ simi
Mo ‘yo lati ri O,
Wo y’o ha koja lori mi
Loni, l’airi bukun? Amin
English »Update Hymn