HYMN 670

C.M.S 460 t. H.C 506 C.M (FE 696)
“Omo na si dagba o si le l'akan."
- Luku.2:40



1.  BI osun gbede eti do 

     Tutu mini-mini 

     B’igbo dudu eti omi 

     B'itanna ipado.


2.  Be l'omo na yio dagba 

     Ti nrin l‘ona rere 

     T’okan re nfa si Olorun 

     Lat‘igba ewe re.


3.  Ewe tutu l'eba odo 

     B'o pe, a re danu 

     Be n’itanna ipa omi 

     Si nre l‘akoko Re.


4.  lbukun ni fun omo na 

     Ti nrin l‘ona Baba 

     Oba ti ki pa lpo da 

     Eni Mimo lailai.


5.  Oluwa, Wo la gbekele

     Fun wa l‘ore ofe

     L’ewe, l‘agba ati n’iku 

     Pa wa mo b'omo Re.  Amin

English »

Update Hymn