HYMN 667

C.M.S 476, 623, t.C 506 L.M (FE 693)
"Mo si ri awon oku ewe......nwon 
duro niwaju Olorun” - Ifi.20:12



1.  AWON kekeke wo l’eyi 

     T'nwon tete l’ajo aiye ja 

     Ti nwon si de ‘bugbe ogo 

     Eyiti nwon ti nf‘oju si?


2.  Emi t’oke Sioni wa 

     Emi lati ile India

     Emi t’ile Afrika wa 

     Emi lat’ erekusu ni.


3.  Irin ajo wa ti koja 

     Ekun ati irora tan

     A jumo pade nikehin 

     Li enu ibode own.


4.  A nreti lati gbo pe, ‘Wa 

     Asegun ese on iku

    Gb’ori nyin soke, ilekun 

    K'awon ero ewe wole.  Amin

English »

Update Hymn