C.M. (FE 692) "Egbe buburu ko se ko" 1. AWON asepe, abura At’awon onija Ni ijo kan pelu abo Niki y’o je s’owo won. 2. Orin buburu ti nwon nko Je rira l’eti mi K’iru oro buburu won Mase t’enu mi bo. 3. Awon alailero omo Awon Omo-komo Ki y’o f;’ijo kan j'egbe mi A f‘ologbon omo. 4. Alailojuti omo kan Ni b‘awon t'o ku je Elekuru obuko kan Ni ko orun w’agbo. 5. Ma je kl nk'egbe buburu Olorun Oluwa, Ki nma si si ninu won Ti nlo s'orun egbe! Amin