ADURA TI O SAJU ONJE C.M.S 484 H.C L.M (FE 689) "O mu isu akara marun ati eja meji O gbe oju sake, O si bu u. O si fi fun awon omo‐ehin Re” - Matt. 14:19 1. WA ba wa jeun, Oluwa Je ka ma yin oruko Re Wa busi onje wa, si je Ka le ba O jeun l’orun. Amin ADURA T’O KEHINONJE H.C 488 L.M “Gbogbo eda Olorun Ii o dara, bi a ba fi ope gba a" - 1Tim 4:4 1. A F’OPE fun O, Oluwa Fun onje wa at’ebun mi; Fi onje orun b’okan wa, Onje iye lat’oke wa. Amin